9 Bẹ́ẹ̀ sì ni ìwọ ni o mú mi jáde láti inú ìyá mi;ìwọ ni o sì mú mi wà láìséwu nígbà tí mo wà ní ọmọ ọmú.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 22
Wo Orin Dafidi 22:9 ni o tọ