9 Má pa mí run pẹlu àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀,má sì gba ẹ̀mí mi pẹlu ti àwọn tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ ìpànìyàn,
Ka pipe ipin Orin Dafidi 26
Wo Orin Dafidi 26:9 ni o tọ