Orin Dafidi 27:12 BM

12 Má fi mí lé ìfẹ́ àwọn ọ̀tá mi lọ́wọ́;nítorí pé àwọn ẹlẹ́rìí èké dìde sí mi,ètè wọn sì kún fún ọ̀rọ̀ ìkà.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 27

Wo Orin Dafidi 27:12 ni o tọ