Orin Dafidi 27:2 BM

2 Nígbà tí àwọn aṣebi bá ń gbógun bọ̀ wá bá mi,tí wọ́n fẹ́ pa mí,àwọn alátakò ati àwọn ọ̀tá mi,wọn óo kọsẹ̀, wọn óo sì ṣubú.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 27

Wo Orin Dafidi 27:2 ni o tọ