Orin Dafidi 27:6 BM

6 Nisinsinyii n óo ní ìṣẹ́gunlórí àwọn ọ̀tá mi tí ó yí mi ká;n óo rúbọ ninu àgọ́ rẹ̀ pẹlu ìhó ayọ̀,n óo sì kọ orin aládùn sí OLUWA.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 27

Wo Orin Dafidi 27:6 ni o tọ