Orin Dafidi 28:1 BM

1 Ìwọ ni mo kígbe pè, OLUWA,ìwọ ni ààbò mi, má di etí sí mi.Nítorí bí o bá dákẹ́ sí min óo dàbí àwọn òkú, tí wọ́n ti lọ sinu kòtò.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 28

Wo Orin Dafidi 28:1 ni o tọ