1 N óo yìn ọ́, OLUWA,nítorí pé o ti yọ mí jáde;o kò sì jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi ó yọ̀ mí.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 30
Wo Orin Dafidi 30:1 ni o tọ