23 Ẹ fẹ́ràn OLUWA, gbogbo ẹ̀yin olódodo,OLUWA a máa ṣọ́ àwọn olóòótọ́,a sì máa san àlékún ẹ̀san fún àwọn agbéraga.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 31
Wo Orin Dafidi 31:23 ni o tọ