Orin Dafidi 32:3 BM

3 Nígbà tí n kò jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi,ó rẹ̀ mí wá láti inú,nítorí kíkérora tí mò ń kérora ní gbogbo ìgbà.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 32

Wo Orin Dafidi 32:3 ni o tọ