Orin Dafidi 37:28 BM

28 Nítorí OLUWA fẹ́ràn ẹ̀tọ́;kò ní kọ àwọn olùfọkànsìn rẹ̀ sílẹ̀.Yóo máa ṣọ́ wọn títí lae,ṣugbọn a óo pa àwọn ọmọ eniyan burúkú run.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 37

Wo Orin Dafidi 37:28 ni o tọ