Orin Dafidi 37:34 BM

34 Gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, sì máa tọ ọ̀nà rẹ̀,yóo gbé ọ ga, kí o lè jogún ilẹ̀ náà;nígbà tí a bá pa àwọn eniyan burúkú run, o óo fojú rẹ rí i.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 37

Wo Orin Dafidi 37:34 ni o tọ