Orin Dafidi 37:40 BM

40 OLUWA a máa ràn wọ́n lọ́wọ́, a sì máa gbà wọ́n;a máa gbà wọ́n sílẹ̀ lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú,a sì máa gbà wọ́n là,nítorí pé òun ni wọ́n sá di.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 37

Wo Orin Dafidi 37:40 ni o tọ