Orin Dafidi 38:15 BM

15 Ṣugbọn, OLUWA, ìwọ ni mò ń dúró dè;OLUWA, Ọlọrun mi, ìwọ ni o óo dá mi lóhùn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 38

Wo Orin Dafidi 38:15 ni o tọ