Orin Dafidi 39:12 BM

12 “OLUWA, gbọ́ adura mi,tẹ́tí sí igbe mi,má dágunlá sí ẹkún mi,nítorí pé àlejò rẹ, tí ń rékọjá lọ ni mo jẹ́;àjèjì sì ni mí, bíi gbogbo àwọn baba mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 39

Wo Orin Dafidi 39:12 ni o tọ