1 Dá mi lóhùn nígbà tí mo bá pè ọ́,Ọlọrun mi olùdániláre.Ìwọ ni o yọ mí nígbà tí mo wà ninu ìpọ́njú,ṣàánú mi, kí o sì gbọ́ adura mi.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 4
Wo Orin Dafidi 4:1 ni o tọ