5 Ẹ rú ẹbọ òdodo,kí ẹ sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA.
6 Ọ̀pọ̀ eniyan ni ó ń bèèrè pé “Ta ni yóo ṣe wá ní oore?”OLUWA, tan ìmọ́lẹ̀ ojú rẹ sí wa lára.
7 Ìwọ ti fi ayọ̀ kún ọkàn miju ayọ̀ àwọn tí ó rí ọpọlọpọ ọkà ati ọtí waini nígbà ìkórè.
8 N óo dùbúlẹ̀, n óo sì sùn ní alaafia,nítorí ìwọ OLUWA nìkan ni o mú mi wà láìléwu.