Orin Dafidi 42:2 BM

2 Òùngbẹ Ọlọrun ń gbẹ ọkàn mi,àní, òùngbẹ Ọlọrun alààyè.Nígbà wo ni n óo lọ, tí n óo tún bá Ọlọrun pàdé?

Ka pipe ipin Orin Dafidi 42

Wo Orin Dafidi 42:2 ni o tọ