9 Mo bi Ọlọrun, àpáta mi pé,“Kí ló dé tí o fi gbàgbé mi?Kí ló dé tí mò ń ṣọ̀fọ̀ kirinítorí ìnilára ọ̀tá?”
Ka pipe ipin Orin Dafidi 42
Wo Orin Dafidi 42:9 ni o tọ