Orin Dafidi 43:5 BM

5 Ìwọ ọkàn mi, kí ló dé tí o fi rẹ̀wẹ̀sì?Kí ló dé tí ara rẹ kò fi balẹ̀ ninu mi?Gbẹ́kẹ̀ rẹ lé Ọlọrun; nítorí pé n óo tún yìn ín,olùrànlọ́wọ́ mi ati Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 43

Wo Orin Dafidi 43:5 ni o tọ