Orin Dafidi 44:2 BM

2 Ìwọ ni o fi ọwọ́ ara rẹ lé àwọn orílẹ̀-èdè jáde fún wọn,tí o sì fi ẹsẹ̀ àwọn baba wa múlẹ̀;o fi ìyà jẹ àwọn orílẹ̀-èdè náà,o sì jẹ́ kí ó dára fún àwọn baba wa.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 44

Wo Orin Dafidi 44:2 ni o tọ