Orin Dafidi 44:26 BM

26 Gbéra nílẹ̀, kí o ràn wá lọ́wọ́!Gbà wá sílẹ̀ nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 44

Wo Orin Dafidi 44:26 ni o tọ