10 Nítorí èmi ni mo ni gbogbo ẹran inú igbó,tèmi sì ni gbogbo mààlúù tó wà lórí ẹgbẹrun òkè.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 50
Wo Orin Dafidi 50:10 ni o tọ