Orin Dafidi 51:10 BM

10 Dá ọkàn mímọ́ sí inú mi, Ọlọrun,kí o sì fi ẹ̀mí ọ̀tun ati ẹ̀mí ìṣòótọ́ sí mi lọ́kàn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 51

Wo Orin Dafidi 51:10 ni o tọ