Orin Dafidi 51:4 BM

4 Ìwọ nìkan, àní, ìwọ nìkan ṣoṣo ni mo ṣẹ̀,tí mo ṣe ohun tí ó burú lójú rẹ,kí ẹjọ́ rẹ lè tọ́ nígbà tí o bá ń dájọ́,kí ọkàn rẹ lè mọ́ nígbà tí o bá ń ṣe ìdájọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 51

Wo Orin Dafidi 51:4 ni o tọ