Orin Dafidi 55:15 BM

15 Jẹ́ kí ikú jí àwọn ọ̀tá mi pa;kí wọ́n lọ sinu isà òkú láàyè;kí wọ́n wọ ibojì lọ pẹlu ìpayà.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 55

Wo Orin Dafidi 55:15 ni o tọ