Orin Dafidi 55:23 BM

23 Ṣugbọn ìwọ, Ọlọrun, o óo sọ àwọn apaniati àwọn alárèékérekè, sinu kòtò ìparun;wọn kò ní lo ìdajì ọjọ́ ayé wọn.Ṣugbọn èmi óo gbẹ́kẹ̀lé ọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 55

Wo Orin Dafidi 55:23 ni o tọ