Orin Dafidi 55:3 BM

3 Ìhàlẹ̀ ọ̀tá bà mí ninu jẹ́,nítorí ìnilára àwọn eniyan burúkú;wọ́n kó ìyọnu bá mi,wọ́n ń bínú mi, inú wọn sì dùn láti máa bá mi ṣọ̀tá.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 55

Wo Orin Dafidi 55:3 ni o tọ