Orin Dafidi 58:11 BM

11 Àwọn eniyan yóo wí nígbà náà pé,“Nítòótọ́, èrè ń bẹ fún olódodo;nítòótọ́, Ọlọrun ń bẹ tí ń ṣe ìdájọ́ ayé.”

Ka pipe ipin Orin Dafidi 58

Wo Orin Dafidi 58:11 ni o tọ