Orin Dafidi 59:5 BM

5 Ìwọ, OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun,Ọlọrun Israẹli,jí gìrì, kí o jẹ gbogbo orílẹ̀-èdè níyà;má da ẹnìkan kan sí ninu àwọn tí ń fi ìwà ọ̀dàlẹ̀ pète ibi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 59

Wo Orin Dafidi 59:5 ni o tọ