11 Ṣugbọn ọba yóo máa yọ̀ ninu Ọlọrun;gbogbo àwọn tí ń fi orúkọ OLUWA búrayóo máa fògo fún un;ṣugbọn a ó pa àwọn òpùrọ́ lẹ́nu mọ́.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 63
Wo Orin Dafidi 63:11 ni o tọ