Orin Dafidi 66:15 BM

15 N óo fi ẹran àbọ́pa rú ẹbọ sísun sí ọ,èéfín ẹbọ àgbò yóo rú sókè ọ̀run,n óo fi akọ mààlúù ati òbúkọ rúbọ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 66

Wo Orin Dafidi 66:15 ni o tọ