Orin Dafidi 67:4 BM

4 Kí inú àwọn orílẹ̀-èdè ó dùn,kí wọn ó máa kọrin ayọ̀,nítorí pé ò ń ṣe ìdájọ́ àwọn eniyan láìṣe ojuṣaaju;o sì ń tọ́ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè ayé.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 67

Wo Orin Dafidi 67:4 ni o tọ