16 Ẹ̀yin òkè olórí pupọ,kí ló dé tí ẹ̀ ń fi ìlara wo òkè tí Ọlọrun fẹ́ràn láti máa gbé,ibi tí OLUWA yóo máa gbé títí lae?
Ka pipe ipin Orin Dafidi 68
Wo Orin Dafidi 68:16 ni o tọ