Orin Dafidi 68:18 BM

18 Ó gun òkè gíga,ó kó àwọn eniyan nígbèkùn;ó gba ẹ̀bùn lọ́wọ́ àwọn eniyan,ati lọ́wọ́ àwọn ọlọ̀tẹ̀ pàápàá.OLUWA Ọlọrun yóo máa gbébẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 68

Wo Orin Dafidi 68:18 ni o tọ