Orin Dafidi 68:33 BM

33 Ẹni tí ń gun awọsanma lẹ́ṣin, àní awọsanma àtayébáyé;ẹ gbọ́ bí ó ṣe ń sán ààrá, ẹ gbọ́ ohùn alágbára.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 68

Wo Orin Dafidi 68:33 ni o tọ