Orin Dafidi 68:6 BM

6 Ọlọrun, olùpèsè ibùjókòó fún àlejò tí ó nìkan wà;ẹni tí ó kó àwọn ẹlẹ́wọ̀n jáde sinu ìdẹ̀ra,ṣugbọn ó sì fi àwọn ọlọ̀tẹ̀ sílẹ̀ ninu ilẹ̀ gbígbẹ.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 68

Wo Orin Dafidi 68:6 ni o tọ