Orin Dafidi 78:18 BM

18 Wọ́n dán Ọlọrun wò ninu ọkàn wọn,wọ́n ń wá oúnjẹ tí yóo tẹ́ ìfẹ́ ọkàn wọn lọ́rùn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 78

Wo Orin Dafidi 78:18 ni o tọ