Orin Dafidi 78:25 BM

25 Ọmọ eniyan jẹ lára oúnjẹ àwọn angẹli;Ọlọrun fún wọn ní oúnjẹ àjẹtẹ́rùn.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 78

Wo Orin Dafidi 78:25 ni o tọ