Orin Dafidi 79:13 BM

13 Nígbà náà, àwa eniyan rẹ,àní, àwa agbo aguntan pápá rẹ,yóo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae;a óo sì máa sọ̀rọ̀ ìyìn rẹ láti ìran dé ìran.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 79

Wo Orin Dafidi 79:13 ni o tọ