Orin Dafidi 8:2 BM

2 Àwọn ọmọ-ọwọ́ ati àwọn ọmọ-ọmú ń kọrin ògo rẹ,wọ́n ti fi ìdí agbára rẹ múlẹ̀,nítorí àwọn tí ó kórìíra rẹ,kí á lè pa àwọn ọ̀tá ati olùgbẹ̀san lẹ́nu mọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 8

Wo Orin Dafidi 8:2 ni o tọ