Orin Dafidi 84:3 BM

3 Àwọn ẹyẹ ológoṣẹ́ pàápàá a máa kọ́ ilé,àwọn alápàáǹdẹ̀dẹ̀ a sì máa tẹ́ ìtẹ́níbi tí wọ́n ń pa ọmọ sí, lẹ́bàá pẹpẹ rẹ,àní lẹ́bàá pẹpẹ rẹ, OLUWA àwọn ọmọ ogun,ọba mi, ati Ọlọrun mi.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 84

Wo Orin Dafidi 84:3 ni o tọ