Orin Dafidi 85:2 BM

2 O dárí àìdára àwọn eniyan rẹ jì wọ́n;o sì bo gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 85

Wo Orin Dafidi 85:2 ni o tọ