Orin Dafidi 86:15 BM

15 Ṣugbọn ìwọ, OLUWA, ni Ọlọrun aláàánú ati olóore;o kì í tètè bínú, o sì kún fún ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, ati òtítọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 86

Wo Orin Dafidi 86:15 ni o tọ