Orin Dafidi 86:17 BM

17 Fi àmì ojurere rẹ hàn mí,kí àwọn tí ó kórìíra mi lè rí i,kí ojú sì tì wọ́n;nítorí pé ìwọ, OLUWA, ni o ràn mí lọ́wọ́,tí o sì tù mí ninu.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 86

Wo Orin Dafidi 86:17 ni o tọ