Orin Dafidi 86:5 BM

5 Nítorí pé olóore ni ọ́, OLUWA,o máa ń dárí jini;ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ sì pọ̀ sí gbogbo àwọn tí ń ké pè ọ́.

Ka pipe ipin Orin Dafidi 86

Wo Orin Dafidi 86:5 ni o tọ