15 Láti ìgbà èwe mi ni a tí ń jẹ mí níyà,tí mo sì fẹ́rẹ̀ kú,mo ti rí ìjẹníyà rẹ tí ó bani lẹ́rù;agara sì ti dá mi.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 88
Wo Orin Dafidi 88:15 ni o tọ