1 OLUWA, tọkàntọkàn ni n óo fi dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ;n óo ròyìn gbogbo iṣẹ́ ìyanu rẹ.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 9
Wo Orin Dafidi 9:1 ni o tọ