2 A ti fi ìdí ìjọba rẹ múlẹ̀ láti ìgbà laelae;láti ayérayé ni o ti wà.
3 Ibú omi gbé ohùn wọn sókè, OLUWA,ibú omi gbé ohùn wọn sókè,ó sì ń sán bí ààrá.
4 OLUWA lágbára lókè!Ó lágbára ju ariwo omi òkun lọ,ó lágbára ju ìgbì omi òkun lọ.
5 Àwọn òfin rẹ kìí yipada,ìwà mímọ́ ni ó yẹ ilé rẹ títí lae, OLUWA.