1 Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á kọrin sí OLUWA;ẹ jẹ́ kí á hó ìhó ayọ̀ sí Olùdáàbòbò ati ìgbàlà wa!
Ka pipe ipin Orin Dafidi 95
Wo Orin Dafidi 95:1 ni o tọ