5 Tirẹ̀ ni òkun, nítorí pé òun ni ó dá a;ọwọ́ rẹ̀ ni ó sì fi dá ìyàngbẹ ilẹ̀.
Ka pipe ipin Orin Dafidi 95
Wo Orin Dafidi 95:5 ni o tọ